Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Rírán Jáde Lọ Ní Méjì Méjì

    Jesu pàsẹ fún àwọn méjìlá láti jáde lọ ní méjì méjì sí àwọn ìlú àti ìletò ní pípè tí ó pè wọ́n nípasẹ̀ ẹ RẸ̀. Kò sí ẹnikẹ́ni tí a rán jáde ní òun nìkan, ṣùgbọ́n ọkùnrin dara pọ̀ mọ́ ọkùnrin, ọ̀rẹ́ pẹ̀lú ọ̀rẹ́. Nípa báyìí, wọn yóò le ṣe ìrànwọ́, wọn yóò sì le gba ara wọn níyànjú, wọn yóò le gba ara wọn ní ìmọ̀ràn, àti láti gbàdúrà papọ̀,ẹnikọọkan ti o lágbára láti gbé aláìlágbára ní ìgbọ̀nwọ́.Ní bákan náà lẹ́yìn eléyì í, Ó rán àwọn àádọ́rin jáde. Ìfẹ́ Olugbala ni pé kí àwọn ìránṣẹ́ ẹ ti ìhìnrere gbọdọ̀ kẹ́gbẹ́ pọ̀ ní ọ̀nà yì í. Ní àsìkò o tiwa yì í, iṣẹ́ ajíhìnrere yóò láṣeyọrí tí wọ́n bá lè tẹ̀lé àpẹẹrẹ yì í dáa dáa.- The Desire of Ages, p.350.IIO 128.1

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents