Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Iṣẹ́ Tí ó láyọ̀

  Iṣẹ́ tí ó láyọ̀ ni láti ṣí Ìwé Mímọ́ fún àwọn ẹlòmíràn. - Testimonies, vol.9, p.118. IIO 144.3

  Ṣí Ìwé Mímọ́ sí àwọn díẹ̀ tí wọ́n wà lókùnkùn, o kò ní le è ṣe àwáwí nípa ti àárẹ̀ tàbí àìnífẹ̀ ẹ́ nínú iṣẹ́ òtítọ́. Ọkàn-àn rẹ yóò sọjí sí àìbalẹ̀ àyà fún àwọn ọkàn, àti ayọ̀ nínú àwọn ẹ̀rí i ti ìgbàgbọ́ yóò kún inú ọkàn-àn rẹ, ìwọ yóò sì mọ̀ pé “Ẹni tí ó ń bomirin ni a yóò bominrin pẹ̀lú”. - Review and Herald, March 13, 1888. IIO 144.4

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents