Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ohun Tí ó Ṣe Pàtàkì Fún Àṣeyọrí

    Ìbágbépò èmí-mímó pèlú àwon òsìsé Olórun yóò fún won ní agbára láti so òtító, agbára tí gbogbo ògo àti olá ayé yìí kò lè fi fún ni.-The Acts of Apostles, p. 51.IIO 253.3

    Olórun kò bi wá láti se pèlú agbára wà isé tó wà níwájú wa. Ó ti pèsè ìraǹlówó àtòrunwá fún gbogbo àwon àtèlé tí agbára ènìyàn kò lè ká. Ó fún wa ní èmí-mímó Èmí-mí-mó láti ràn wá lówó nínú gbogbo ìdènà, láti ran ìrètí wa lówó àti ìdánilójú, láti bá okàn wa pàdé àti láti so okàn wa di mímó.-Southern Watchman, Aug. 1, 1905.IIO 253.4

    Nigbà tí èmí-mímó sòkalè, àwon omo èyìn kún fún ìfé Krístì àti àwon tí ó kún fun òpòlopò okàn ni ó yò nípasè òrò tí wón so àti àdúrà tí wón gbà. Wón sòrò ní agbára èmí-mímó àti nípasè agbára ńaà, òpòlopò èmí tí a ràpadà.-The Acts of Apostles, p. 22.IIO 253.5

    Kò sí òdiwòn fún ìwúlò eni tí ó gbé ara rè ségbèé, tí ó sì fi ààyè gba isé èmí-mímó lókàn rè, tí ó sì ń gbé ayé ti Krístì.-Southern Watchman, Aug. 1, 1905.IIO 253.6

    Kí ni èrè tàbí àbáyorí òjò èmí-mímó ní ojó Péńtékòstì? Isé ìhìnrere ti Kristi tí ó jíǹde dé gbogbo ayé Nípasè isé won, òpòlopò àwon tí a yàn ni ó darapò mó ìjo, àwon tí ó fi ayé won jì, isé Olórun, nígbà tí wón gba òrò ìyè, àwon tí wón fi ayò àti ìrètì kún okàn won bí wón ti fi òrò ìrètí yìí tàn kálè. Òpòlopò ni ó so orọ̀ náà “Ìjoba òrun kù sí dèdè”. Wo ò dánu dúró bí ìdèrùbà tipọ̀ tó. Olórun gba enu won sòrò, ní gbogbo ibi tí wón sì lo, aláìsàn rí ìwòsàn, àwon aláìní rí òrò ìyè gbà. Lópòlopò ni Olórun lè sisé tí omo ènìyàn bá fi ara won jìn fún ìtósónà. - Southern Watchman, Aug. 1, 190).IIO 254.1

    Èmí-mímó ni èmí àyè ìgbàgbó nínú okàn. Fífi èmí-mímó fún ni jé fífi ayé Kristi fún ni. Ó ń fi àmúye Kristi fún eni tí ó bá gbà á, gbọ́ tí a bá kó nípa Olórun nìkan, àwon tí ó gba isé èmí-mímó nínú okàn won, tí a sì gbé Kristi ga nínú ayé won, ni ó lè dúró gégé bí asojú, tó lè jíhìnrere fún ìjo.-The Desire of Ages, p. 803.IIO 254.2

    Ìyàtò tí ó tayo, tí ó sì yàtò yóò selè, àwon ènìyàn Olórun yóò sì rí èbùn èmí-mímó gbà, yóò lè jé pé pèlú ogbón òrun won á lè kojú àwon ohun àìròtélè ayé yìí, won kò sì tún lè kojú ìwà ìbàjé ayé yìí. Tí ìjo kò bá sùn, tí àwon òsìsé ń sónà nínú àdúrà, won kò lè ní ìmólè láti mòye àti mo rírì isé tàbí ìrìn àwon òtá.-Testimonies, Vol. 6, p. 436.IIO 254.3

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents