Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Èrè Olódodo

    Olúwa dára.Ó ní àánú àti ọkàn tí ó nífẹ̀ ẹ́. Ó ní àbáṣepọ̀ pẹ̀lú ẹnìkọ̀ọ̀kan tí ó jẹ́ ọmọ ọ Rẹ̀. Ó mọ ohun tí ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn ń ṣe. Ó mọ èrè tí ó yẹ kí ó fún wọn. Ṣé o kò ní to ìwà rere è rẹ àti ìdálébi ì rẹ jọ, kí ó sì jẹ́ kí Ọlọ́run ṣe iṣẹ́ ẹ Rẹ̀? A yóò fi adé ògo fún ọ tí o bá ṣe iṣẹ́ tí Ọlọ́run fi fún ọ láti ṣe.- Southern Watchman, May 14, 1903.IIO 268.3

    Ọlọrun fẹ́ kí a sinmi nínú u Rẹ̀ láì béèrè tàbí ní èdùn ọkàn nípa èrè e wa. Nígbà tí Jésù bá ń gbé inú ọkàn,èrò èrè gbígbà kì í ṣe ohun tí ó ṣe pàtàkì jùlọ,èyí kì í ṣe ìdí tí a fi ń ṣiṣẹ́.- Christ’s Object Lessons, p.398.IIO 268.4

    Láti orí òkè gegele, ihò, ògbun, ihò inú omi, aṣálẹ̀ ni Ọlọ́run ti mú àwọn ọmọ ọ rẹ̀ wá padà sọ́dọ̀ ọ Rẹ̀. Nínú ayé, wọ́n ti jìyà. Ọ̀pọ̀pọpọ̀ ló kú pẹ̀lú ìjìyà àti àpá nítorí pé wọ́n kọ̀ láti ṣẹ́ Jésù, nípa kíkọ iṣẹ́ àti ẹ̀tàn sàtánì. Nípa ìnà àti iṣẹ́ ọmọ ènìyàn, a ti dá àwọn òṣìṣẹ́ Ọlọ́run lẹ́jọ́ gẹ́gẹ́ bí ọ̀daràn.Ṣùgbọ́n ọjọ́ náà kù sí dẹ̀dẹ̀ nígbà tí “Ọlọ́run yóò jẹ́ adájọ́ fúnra a Rẹ̀”.Nígbà tí a yóò sì yí àwọn ìpinnu ayé yìí padà.”Ìkọ̀sílẹ̀ àti ìjìyà àwọn ènìyàn a Rẹ̀ la yóò sì mú kúrò” Aṣọ funfun ni a yóò sì fi wọ ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn.a”yóò sì pè wọ́n ní ènìyàn mímọ́, àwọn ẹni ìràpadà a ti Olúwa”.- Christ’s Object Lessons, pp.179,180.IIO 268.5

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents