Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Àwọn Òjíṣẹ́ Ọlọ́run Oníhìnrere Oníṣègùn

    Àwọn òṣìṣẹ́- ti o jẹ Oníhìnrere oníṣègùn- ni a nílò báyìí.O kò le è lo ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún fún ìgbáradì. Láìpẹ́ àwọn ilẹ̀kùn tí a ṣí sílẹ̀ fún òtítọ́ yóò tì. Ní báyìí gbé ìhìnrere náà, máṣe dúró, láti jẹ́ kí àwọn ọ̀tá gba àwọn ilẹ̀ tí ó ṣí sílẹ̀ níwájú ù rẹ ní ìní. Jẹ́ kí àwọn ẹgbẹ́ kékeré jáde lọ láti ṣiṣẹ́ èyí tí kristi yan àwọn ọmọ ẹ̀hìn-in RẸ̀. Jẹ́ kí wọn ṣiṣẹ́ bí ajíhìnrere, fífọ́n àwọn ìwé àtẹ̀jáde káàkiri, kí wọn sì sọ̀rọ̀ òtítọ́ fún àwọn tí wọ́n bá bá pàdé. Jẹ́ kí wọn gbàdúrà fún àwọn aláìsàn, kí wọn bá àìní i wọn pàdé, kì í ṣe pẹ̀lú àwọn oògùn, ṣùgbọ́n pẹ̀lú àwọn atunṣe nipa iṣẹda, àti ṣíṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ bí a ṣe lè dá ìlera a wọn padà àti láti yàgò fún àìsàn.- Testimonies, vol.9. p.172.IIO 128.3

    Ará lọ́kùnrin àti lóbìnrin, ẹ fi ara yín fún Ọlọrun fún iṣẹ́ ìsìn. Máṣe jẹ́ kí ànfààní kankan kọjá láì ṣe àtúnṣe. Bẹ aláìsàn àti ẹni tí ó ń jìyà wò, kí o sì fi ìfẹ́ àánú u rẹ̀ hàn sí wọn. Tí ó bá ṣe é ṣe, ṣe n kàn kan tí ó lè mú kí wọn wà ní ìrọ̀rùn sí i. Nípa àwọn ọ̀nà yì í o le è dé àwọn ọkàn-an wọn, kí o sì sọ̀rọ̀ Kristi fún wọn. Ayérayé nìkan yóò sì ṣàfihàn bí irú ọ̀nà iṣẹ́ náà yóò ṣe rí.Àwọn ọ̀nà tí ó tún wúlò yóò ṣí sílẹ̀ níwájú àwọn tí wọ́n fẹ́ láti ṣiṣẹ́ náà nítòsí i wọn.- Testimonies, vol.9, p.36.IIO 128.4

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents