Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ẹ̀mí Mímọ́ Ń ṣiṣẹ́ Láti Ìbẹ̀rẹ̀ Wá

    Láti ìbèrè pèpè ni èmí-mímó ti ń sisé nípa lílo omo ènìyàn láti se ìfé Rè fún ìran tí ó subú. Èyí farahàn nínú ayé àwon baba-ń lá wa. Sí ìjo tó wà nínú aginjù pèlú, ní ayé Mósè, Olórun f’èmí tí ó dára fún won, láti darí won. Béè ní ayé àwon àpóstélì, ó sisé kárakára fún ìjo rè nípasè àwon ìránsé èmí-mímókan náà tí ó gba àwon baba-ń là wa, tí ó fún Kálébù àti Jóshúà ní ìgboyà àti ìgbàgbó, tí ó jé kí ìse àwon Ìjo Àpóstélì se déédéé, tí ó mú àwon omo Olórun tí ó nígbàgbó dúró ní gbogbo ìgbà. Nípasè agbára èmí-mímó yìí ni Krìsténì Waldensian se lè se ìrànlówó láti pèsè ònà ìyípadà rere nígbà ayé dúdú. Agbára yìí kan náà ni ó jé kí isé àwon èmí òótó tí ó bèrè isé ìsìn ti òde òní àti síse ògbifò ọ Bíbélì sí orísirísi èdè àwon ènìyàn yorí sí rere.-The Acts of Apostles, p. 53.IIO 256.1

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents