Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  ORÍ KEJÌDÍNLÓGÚN ÌPÀGỌ́ JẸ́ Ọ̀NÀ ÌRÀNLỌ́WỌ́ NÍNÚ IṢẸ́

  ÌGBÀGBỌ́

  Ìpàdé ìpàgọ́ jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ètò pàtàkì nínú iṣẹ́ wà. Ó jẹ́ ọ̀nà gbòógì tí a lè fi pe àkíyèsí ọkàn àwọn ènìyàn.-Testimonies, Vol. 6, p. 31.IIO 194.1

  Nínú iṣẹ́ wọ̀yìí, a ní ìpòrúúru ọkàn nípa ọ̀nà tí a lè gbà ṣẹ́gun ẹ̀tanú àti ìwà ìbàyéjẹ́ àti ọ̀nà tí a lè gbà mú òtítọ́ tí ó ṣọ̀wọ́n wá sí ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn gbogbo. Ọlọ́run ti jẹ́ kí ó di mímọ fún wa wí pé ìpàdé ìpàgọ́ ni irinṣé tí a lè lò fún àṣeyọrí iṣẹ́ yìí.-Testimonies, Vol. 6, pp. 31, 32.IIO 194.2

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents