Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Gbèdéke Láti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run

    Olúwa ń fẹ́ kí a gba gbogbo ẹ̀kọ́ tí ó yẹ pẹ̀lú ohun tí ó wà níwájú u wa ní èrò láti fi kọ́ àwọn ẹlòmíràn. Kò sí ẹni tí ó mọ ibi tàbí báwo ni wọ́n ṣe le pè wọ́n láti ṣiṣẹ́ tàbi sọ̀rọ̀ fún Ọlọ́run. Bàbá a wa tí ń bẹ lọ́run nìkan rí ohun tí ó lè mú jáde láti ara ènìyàn. Àwọn ohun tí a lè ṣe wà níwájú u wa èyí tí àìlera ìgbàgbọ́ ọ wa kò jẹ́ kí a mọ̀. Ọkàn an wa ni a gbọdọ̀ kọ́ pé tí ó bá ṣe é ṣe a lè gbé òtítọ ọ̀rọ̀ ọ Rẹ̀ síwájú àwọn aláṣẹ ayé tí ó ga jù ní ọ̀nà láti fi yin orúkọ ọ Rẹ̀ lógo.- Christ’s Object Lessons, pp.333,334.IIO 62.4

    Àwọn wo ni ó ti gbáradì láti lọ ṣiṣẹ́ nínú ọgbà àjàrà a Rẹ̀? Ọlọ́run kò ní inú dídùn sí aláìmọ̀kan. Ó fẹ́ kí a lo ohun tí ó dára jùlọ àti ohun tí ó ga níti àwọn ẹ̀bùn tí ó ti fifún wa.- Review and Herald,April 2, 1889.IIO 62.5

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents