Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Àwòkọ́ṣe Fún Ètò ṣíṣe ìjọ

    Ṣíṣe ètò ìjọ ní Jérúsálẹ́mù jẹ́ bí àwòkọ́ṣe fun eto àwọn ìjọ níbò míràn níbi tí àwọn òjíṣẹ́ ti òtítọ́ gbọdọ̀ jèrè ọkàn sínú ìhìnrere. Níkẹhìn nínú ìtàn ti ìjọ àkọ́kọ́, nígbà tí onírúurú ipa ti àgbáyé ọ̀pọ̀ ẹgbẹ́ onígbàgbọ́ ni wọ́n ti dá sílẹ̀ nínú àwọn ìjọ, kíkójọ ìjọ ni a sọ di pípé níwájú, kí a ba à lè mú ètò àti ìwà ní pípé rẹ̀ dúró. Ọmọ ìjọ kọ̀ọ̀kan ni a gbà níyànjú láti ṣapá a rẹ̀ dáadáa, ẹnì kọ̀ọ̀kan ni ó sì ní láti lo àwọn ẹ̀bùn tí a fún un dáadáa. - The Acts of the Apostles, pp.91, 92.IIO 73.5

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents