Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    ORI KERINDINLOGBON ÌDÁNILÓJÚ ÀSEYORÍ

    Ẹri Ọrun

    Olórun yóò se isé náà tí a bá pèsè irin isé tí ó tó.-Testimonies, Vol. 9, p. 107.IIO 257.1

    Olórun yóò gba ìsìn tí a se tokàn-tokàn, yóò sì dí gbogbo kùdìè-kudie.-The Ministry of Healing, p. 150.IIO 257.2

    Gbogbo isé òtító yóò wà láíláí, eni tí ó se isé òtító lè rò pé òun kò se ohun kan tí a le tóka sí sùgbón isé rere yìí yóò wà títí láí.-Testimonies, Vol. 2, p. 683.IIO 257.3

    Tí a bá yà ó sótò nítòótó, Olórun yóò ti ara re yan àwon mìíràn tí yóò mú ìmólè wo ọ̀dò àwon tó wà nínú òkùnkùn (Testimonies, Vol. 7, p. 63).IIO 257.4

    Òtító yóò borí pèlú ògo tí ó tayo, gbogbo àwon tí ó sì yàn láti jé òsìsé pèlú Olórun yóò tayo pèlú u Rè.-Testimonies, Vol. 9, p. 135.IIO 257.5

    Fún gbogbo ènìyàn tí ó fara rè jìn fún isé Olúwa pátápátá ni a fi agbára fún láti rí àbáyorí tí kò légbé.-Testimonies, Vol. 7, p. 30.IIO 257.6

    Nígbà tí a bá sisé dáradára fún ìgbàlà àwon ará wa, Olórun yóò mú làálàá wa dé ibi àseyorí.-Testimonies, Vol. 9, p. 83.IIO 257.7

    Olórun ní ààyè fún gbogbo ènìyàn nínú ìlànà Rè. Kìí fún ni ní èbùn tí kò wúlò, tí ẹ̀bùn náà bá tilè kéré, Olórun ní ààyè fún, èbùn kékeré yìí nàá, tí a bá fi ìgbàgbó lòó, yóò sisé tí Olórun fé kí ó sé.-Testimonies, Vol. 9, p. 37.IIO 257.8

    Àwon òsìsé tí ó ní ìrèlè jùlo pèlú ayó sípò Jésù, lè se isé tí ó mi gbogbo ayé tìtì, tí ó sì fi ayò fún gbogbo ayé títí láíláí.-The Ministry of Healing, p. 159.IIO 257.9

    Àbáyorí tòótó nínú isékísé kìí se ohun tí ó wá láìrò télè, ó jé èsì isé àsekára olá Olúwa, èrè ìgbàgbó, ìmò, ìsedéedé àti ìfaratì. Opolo tí ó pé àti ìhùwà ní ònà tí ó ye kò wá ní ònà àìmòdí. Olórun fi ànfààní sílè, àseyorí agbára dá lórí i bí a bá se ló tàbí se é.-Prophets and Kings, p. 486.IIO 257.10

    Àwon tí ó ní ìwúrí láti bèrè isé náà, bóyá nílé, lóko gbodò lo síwájú ní orúko Olúwa. Tí wón bá gbára lé Olórun fún ore-òfé àti agbára, won yóò yege. Ní ìbèrè isé wón lè kéré, sùgbón tí wón bá tèlé ìlànà Olórun, á di púpò Olórun wa. Yóò se é se fún àwa tí ó mo tara won nìkan, tí ó fi ara won jìn, irú enikéni tí kò bá à jé àti níbi gbogbo.-Southern Watchman, Apr. 9, 1903.IIO 258.1

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents