Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ìdánwò Tí a yóò Bá Pàdé

    Ní ìkẹhìn iṣẹ́ ọlọ́wọ̀ yìí,díẹ̀ nínú àwọn ènìyàn alágbára ni á ò fún ní’ṣẹ́. Wọ́n tó tán, wọ́n l’ómìnira ti Ọlọ́run. Kò sì le è lò wọ́n.Olúwa ní àwọn ọmọ ẹ̀yiǹ olóótọ́,ní àsìkò mímì, àsìkò ìdánwò ni a o fi han àwọn díẹ̀. Àwọn tó jẹ́ iyebíye tí ó pamọ́ nísinsinyìí tí wọn kò fi orúnkún un wọn kúnlẹ̀ fún òrìṣà a Báálì. Wọn kò tíì ní ìmọ́lẹ̀ ìtànsán èyí tí ó ti ń tàn sórí ì rẹ. Ṣùgbọ́n, ó lè jẹ́ abẹ́ pàlàpálá àti ibi ti kò fani mọ́ra láti ìta ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ mímọ́ tí ìwà àwọn onígbàgbọ́ tòótọ́ ni a ó fihàn. Ní ọ̀sán gangan, à ń wojú ọ̀run, ṣùgbọ́n a kò rí àwọn ìràwọ̀. Wọ́n wà níbẹ̀ bí a kò tilẹ̀ rí wọn ṣùgbọn ojú kò lè sọ ìyàtọ̀ ọ wọn. Ní àṣálẹ́ a máa rí ojúlówó ìmọ́lẹ̀ dídán an rẹ̀.IIO 49.2

    Àsìkò yìí kò fi bẹ́ẹ̀ jìnnà, nígbà tí ìdánwò yìí má a wà fún ọkàn kọ̀ọ̀kan....Ní àsìkò yìí, a ó ò yọ wúrà kúrò nínú ìdàrọ nínú ilé Ọlọ́run. A o mọ ìyàtọ̀ láarin ìwà bí Ọlọ́run tòótọ́ ṣákáṣáká sí ayédèrú ìtànsán ohun tí ń tàn. Ọ̀pọ̀ tí ó jẹ́ bí ìràwọ̀ tí a nífẹ̀ ẹ́ nítorí òye e wọn, yóò jáde sínú òkùnkùn. Ìyàngbò bi ìkuuku ni afẹ́fẹ́ yóò gbé lọ níbi tí a ti rí ojúlówó àlìkámà.Gbogbo àwọn tí ó ṣe àfijọ ohun ọ̀ṣọ́ ti ibi mímọ́, ṣùgbọ́n tí wọn kò lè fi aṣo òdodo Krístì wọ̀, yóò jáde nínú ìtìjú ìhòhò o wọn.- Testimonies,vol.5, pp.80,81.IIO 49.3

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents