Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Pe Àwọn Ènìyàn Sí Ilé è Rẹ Fún Ẹ̀kọ́ ọ Bíbélì

    Pe àwọn aládúgbò ò rẹ sí ilé è rẹ, kí o sì ka Bibeli tí ó ṣe iyebíye àti ìwé tí ó ṣàlàyé òtítọ́ pẹ̀lú u wọn. Rọ̀ wọ́n láti wà papọ̀ pẹ̀lú ù rẹ nínú orin kíkọ àti àdúrà gbígbà. Jésù Kristi náà yóò wà nínú àwọn àkójọpọ̀ kékeré yìí gẹ́gẹ́ bí ó ṣe ṣèlérí, àwọn ọkàn yóò sì ní ìfọwọ́bà nípa oore- ọ̀fẹ́ ẹ RẸ̀. - The Ministry of Healing, pp. 152.153.IIO 122.1

    Nígbà tí wọ́n wà ní Éfésù, Àpóllò. “Bẹ̀rẹ̀ sí sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ìgboyà nínú u Sínágọ́ọ̀gù.” Lára àwọn olùgbọ́ ọ rẹ̀ ni Àqúílà àti Prìcílíà wà àwọn tí wọ́n wòye pé kò tí i ní ìmọ̀ kíkún nínú ìmọ́lẹ̀ ìhìnrere, “wọ́n mú u lọ sí ọ̀dọ̀ ara a wọn, wọ́n sì sọ àsọyé pẹ̀lú u rẹ̀ nípa ọ̀rọ̀ Ọlọ́run dájúdájú”. Nípa ẹ̀kọ́ kíkọ́ ọ wọn ó ní òye pérépéré nínú ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, ó sì di ọ̀kan nínú àwọn alágbàwí tí ó lágbára nínú ẹ̀sìn onígbàgbọ́.- The Acts of the Apostles, p.270.IIO 122.2

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents