Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Èkọ Kan Lára Ìbàkù Àwọn Ísírẹ́lì Ìgbà a Nì.

  Nígbàtí àwon omo Isreli wó ilè Kenaní, won kò mú ìpinnu Olórun se nípa gbígba gbogbo ìlé náà pátápátá. Nígbàtí wón tí borí ní abala kàn, ńse ni wón jókò lójúkannà láti máa je èrè ìségun won. Nínú àìgbàgbó won, ìfé won sí ìgbádùn, wón jókò sí abala ibi tí wón ti ségun nìkan, kàkà tí won ì bá tèsíwájú láti gba àwon agbègbè tuntun. Nípa béè, wọ́n bèrè sí ní kọ Olórun sílè. Nípa ìbàkù won láti tèsíwájú nínú ìpinnu Olórun èyí tí kò sì jẹ́ kí ó ṣeéṣe fún won láti gba àwon ìbùkún tí Ó tí pèsè fún wọn. Ǹjé ìjo òde òní kò máa se irú àsìse béè lónì bi? Pèlú gbogbo àgbáyé níwájú wọn tí won ń pòǹgbe ìhìnrere, ńse ní àwon Onígbàgbó jókò níbití àwon pàápàá tí ní àǹfaàní láti máa gbó ìhìnrere. Won kò rí ìdí tí ó fi se pàtàkì fún láti lọ gba àwon agbègbè tuntun, kí won sì máa polongo ìgbàlà lọ sí àwon agbègbè mìrán. Wón kò láti tèlé ìfilólè Kristi tí ó so wípé, “Ẹ lo sí gbogbo ayé kí e sí máa wàásù ìhìnrere fún gbogbo ènìà”. Ǹjé àwon náà kò jèbi irú èyí tí àwon ìjo Júù jẹ́.-Testimonies, Vol. 8, p. 11a. IIO 185.1

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents