Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Àìmọ Rírì Ìlérí Náà

    Kristi so pé ipa èmí-mímó yóò wà pèlú àwon àtèlé Òun títí dé òpin, sùgbón won kò mò rírì ìlérí yìí bí ó ti ye, fún ìdí èyí, a kò rí ìmúse Rè bí ó ti tò. Ìlérí èmí-mímó jé ohun tí òpòlopò kìí ronú nípa, ìyorísí rè sì jé ìrèwèsì nínú èmí, òkùnkùn nínú èmí, ìfàséyìn nínú èmí, àti ikú. Àwon ohun kékeré gba okàn so, agbára òrun tí ó sì se pàtàkì fún ìdàgbàsókè ìjo Olórun, tí ó fi ìbùkún fún gbogbo àwon tí ó wà nínú ìjo kò sí, bí ó tilè jé pé àwa ni òpò tí a bèèrè.-Testimonies, Vol. 8, p. 21.IIO 255.1

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents