Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Di Òtítọ́ Tí a Tẹnumọ́ Mú.

  Ní ọ̀pọ̀ ìgbà, bí ó ṣe ń wá ọ̀nà láti gbé òtítọ́ kalẹ̀, àtakò yóò dìde; ṣùgbọ́n tí o bá wá ọ̀nà láti pàdé àtakò pẹ̀lú u iyàn jíjà, yóò mú ọ dàkún-un ni, èyí ni o kò lè fi agbára ṣe. Gba òtítọ́ tí a tẹnumọ́ mú. Àwọn ángẹ́lì Ọlọrun ń wò ọ́, wọ́n sì ní òye láti tẹ̀ ẹ́ mọ́ àwọn tí ó kọ àtakò àti àríyànjiyàn- an wọn pàdé. Má gùnlé àwọn kókó àwọn ìbéèrè tí ó le mú iyàn jíjà wá. Ṣùgbọ́n kó àwọn òtítọ́ tí a tẹnumọ́ yìí jọ sí ọkàn-àn rẹ, kí o sì dì wọ́n síbẹ̀ pẹ̀lú àdúrà tí a fi ìtara gbà àti ọkàn ìyàsí mímọ́.- Testimonies, vol.9, pp.147,148.IIO 126.2

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents