Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Aláàánú ni Olórun wa

  Ó kún fún ìkédùn, Ó sì ní ogbón nínú gbogbo àkosílè Rè, kò fé isé tí ó léwu fún ìlera wa nínú ìlàkàkà wa tàbi tí ó rèwèsì agbára okàn wa. Kò ní fé kí a sisé nínú ìpòruurù okàn, títí tí a yóò fi rèwèsì pátápátá àti àìlókun àwon isan wa. Olórun ti fún wa ní ìdí, ó fé kí a má dárayá ní gbogbo ìgbà, kí a sì má gbé ayé wa pèlú ìlànà tí ó sì fi lélè, kí a má gbónràn kí a lè ní ayé tí ó pé. Bí ojó ti ń gorí ojó pèlú gbogbo ohun tí a ní láti se, a gbodò se isé tí ó ye ká se ní òla ní òní. Òsìsé Olórun gbodò mo bí ìwà rè se ní iye tó, kí won sì gbáradì fún isé òla nípa lílo èmí won dáradára.-Review and Herald, Nov. 7, 1893.IIO 248.2

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents