Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Àwọn Ọlọ́rọ̀ Tí Ó Wà Nínú Bíbélì

  Ọkùnrin ará Etopia yẹn jẹ́ ẹni rere tí ó sì jẹ́ alágbàrá láwùjọ. Ọlọ́run mọ̀ wí pé nígbà tí ó bá yípadà, yóò fún àwọn elòmíràn ní ìmọ́lẹ̀ tí ó ti rí gbà, yóò sì lo agbára rẹ̀ láti tan ìhìnrere kalẹ̀. Àwọn angẹ́lì lọ́run dúró láti ṣe àwárí àwọn tí ń wá ìmọ́lẹ̀ wọ́n sì ń fà wọ́n lọ sí ọ̀dọ̀ Olùgbalà. Nípasẹ̀ iṣẹ́ ìránṣẹ́ Ẹ̀mí Mímọ́ ni Olúwa ti máa ń darí àwọn ènìyàn lọ sí ọ̀dọ̀ ẹni tí yóò fi ìmọ́lẹ̀ hàn wọ́n.-The Acts of Apostles, p. 107.IIO 204.3

  Nígbà tí àwọn Júù fẹ́ pa ìjọ run nígbà tí ó ṣẹ̀ẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀ẹ̀rẹ̀, Níkódémù sì jáde wá ó sì dáàbó bòó. Ó lo ipò rẹ̀ làti mú ìgbàgbọ́ àwọn ọmọlẹ̀yìn rẹ̀ dàgbà, ó sì mú kí ìjọ gbèèrú si ní Jérúsálẹ́mú àti ní mímú kí ìhìnrere ó tẹ̀síwájú. Àwọn tó ti ń fi ígbàkan tẹ̀lé e bu ọlá fún un wá bẹ̀rẹ̀ síí ní kẹ́gàn rẹ̀, tí wọ́n sì ń pọ́n-ọn lójú, ó sì di tálákà nínú ohun ayé síbẹ̀ kò dẹ́kun nínú dídáàbò bo ìgbàgbọ́ rẹ.-The Acts of Apostles, p. 105.IIO 205.1

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents