Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ọ̀rọ̀ Àmì Onígbàgbọ́

    Àwọn ọ̀rọ̀ àmì mẹ́ta ni ó wà nínú ayé onígbàgbọ́, tí a ní láti kíyèsí tí a kò bá fẹ́ kí èṣù kó borí i wa; àwọn wọ̀nyí ni ṣọ́ra, gbàdúrà,ṣiṣẹ́.- Testimonies, vol.2, p.283.IIO 106.3

    Gbogbo ọkàn tí ó bá ti jẹ́wọ́ Krístì ti fi ara a wọn jẹ́jẹ́ láti jẹ́ ohun gbogbo tí ó ṣe é ṣe Fún-un láti jẹ́ òṣìṣẹ́ ẹ ti ẹ̀mí, láti ṣaápọn, ní ìtara, àti láti lágbára nínú iṣẹ́ Olúwa a rẹ̀. Ọlọrun ń retí kí ẹnìkọ̀ọ̀kan ṣe iṣẹ́ ẹ rẹ̀, jẹ́ kí eléyìí jẹ́ ọ̀rọ̀ àmì jákè jádò àwọn ẹgbẹ́ ẹ ti àtẹ̀lé e RẸ̀.- Testimonies, vol.5, p.460.IIO 106.4

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents