Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ìkìlọ̀ Tí ó Bọ́ Sí Àsìkò

    A nílò iṣẹ́ ṣíṣe létò létò; Ṣùgbọ́n níbi tí àwọn kan nínú u yín ti ń lo ọ̀pọ̀lọpọ̀ àsìkò láti gbèrò, àti láti ṣètò,ní gbígbáradì fún iṣẹ́, Sátánì á gba iwájú pẹ̀lú ìtàn asán tó kún fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ewu,ọkàn àwọn ènìyàn yóò sì fà si ìṣìnà olórí ẹlẹ́tàn.- Review and Herald, March 13,1888. IIO 75.4

    Báwo ni inú èṣù ì bá ṣe dùn tó tí ó bá jẹ́ pé ó ṣe àṣeyọrí nínú ìyànjú u rẹ̀ láti wọ àarin àwọn yìí, kí ó sì da iṣẹ́ ẹ wọn rú ní ìgbà tí o yẹ ki ijọ wa leto leto,ti yóò sì jẹ́ agbára ń lá láti dá àìsóótọ́ dúró àti láti járọ́ ètekéte tí ó tako ọ̀rọ̀ Ọlọ́run! A fẹ́ ṣe ohun gbogbo lọ́nà tí ó tọ́ láti rí i dájú pé ètò ìjọ kò mẹ́hẹ àti iṣẹ́ tí a ti fi ọgbọ́n àti ẹ̀sọ̀ gbé kalẹ̀. A kò gbọdọ̀ gba àwọn mọ̀ ǹ dàrú tí wọn á fẹ́ gba ìsàkóso láti darí iṣẹ́ ní àkókò yìí láàyè.- Gospel Workers, p.487.IIO 76.1

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents