Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Àwọn Àmúyẹ Òṣìṣẹ́ Pàtàkì

  Àwọn kan yẹ láti ṣiṣẹ́ níbití àwọn ènìyàn ńláńlá wà. Ó yẹ kí irú àwọn òṣìṣé bẹ́ẹ̀ bèèrè ọgbọ́n lọ́dọ̀ Ọlọ́run láti mọ̀ bí wọn yóò ṣe wàásù fún wọn, kìí ṣe láti bá wọn dọ́ọ̀rẹ́ nìkan lásán ṣùgbọ́n nípa jíjẹ́ àpẹẹrẹ ìgbàgbọ́ rere, tí wọ́n yóò sì ti ipa rẹ̀ mú àìní àwọn ọkàn tó yí wọn ká, èyí tí yóò lè mú kí wọ́n ní ìmọ̀ òtítọ́ gẹ́gẹ́ bí ó ti wà nínú Jésù.-The Ministry of Healing, p.213.IIO 203.3

  Ẹ jẹ́ kí àwọn tí wọn yóò ṣiṣẹ́ ní àwọn ibi gíga wọ̀nyìí ó fi ara wọn sí ipò ọ̀wọ̀ tóótọ́, kí wọn ó sì mọ̀ wí pé àwọn ni àwọn angẹ́lì gẹ́gẹ́ bí alábàárìn wọn. Ẹ jẹ́ kí wọn fi ọ̀rọ̀ Olọ́run gẹ́gẹ́ bí a ṣe kọọ́ sínú Bíbélì kún ìṣura ọkàn wọn.-The Ministry of Healing, p. 215.IIO 203.4

  Ní gbogbo akitiyan láti jèrè ọkàn àwọn ọlọ́rọ̀ wọ̀nyìí, àwọn òṣìṣẹ́ Ọlọ́run gbọ́dọ̀ ní ìgbàgbọ́ tí ó lágbára. Ìrínisí lèè dààbí okùn tí kò dára, ṣùgbọ́n ìmọ́lẹ̀ àtòkèwá yóò wà nínú okùnkùn birimù birimù.-The Acts of Apostles, p. 242.IIO 203.5

  Ọlọ́run ń pé àwọn òṣìṣẹ́ tó ní ìtara tí wọ́n sì ní ìrẹ̀lẹ̀, èyí tí yóò mú iṣẹ́ ìhìnrere lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn ńlá ńlá.-The Acts of Apostles, p. 140.IIO 203.6

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents