Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Iṣẹ́ Ìránṣẹ́ ẹ Ti Orin

    Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n ti kọ́ láti kọ àwọn orin ìhìnrere dídùn pẹ̀lú orin dídùn àti ìyàtọ̀, lè ṣe ohun dáradára bí i Ọlọ́rin ajíhìnrere.Wọn yóò rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ààyè láti lo ẹ̀bùn tí Ọlọ́run ti fún wọn nípa gbígbé adùn àti ìtànṣán rẹ̀ lọ sí ọ̀pọ̀ ibi tí ó dáwà tí òkùnkùn ìbànújẹ́ àti ìpọ́njú ṣú bò, kí kọrin sí àwọn tí wọ́n lánfààní láti lọ sí ilé ìjọ́sìn lẹ́ẹ̀kọ̀ọkan. IIO 66.1

    Àwọn akẹ̀kọ̀ọ́, jáde lọ́ sí òpópónà àti ọ̀nà gbóóró kí wọn gbìyànjú láti dé ọ̀dọ̀ àwọn gíga àti àwọn tí wọ́n wà ní ìsàlẹ̀, kí wọn wọ ilé ọlọ́rọ̀ àti tálákà, bí ó ṣe ní ààyè, bèèrè, “Ǹ jẹ́ o o fẹ́ kí a kọ orin díẹ̀ nínú orin ìhìnrere”? nígbà náà, bí àwọn ọkàn bá sì ti ń rò, ààyè lè ṣí sílẹ̀ fún ọ láti gbàdúrà fún ìbùkún Ọlọ́run. Kì í ṣe ọ̀pọ̀ ni yóò kọ́ láti fetí sílẹ̀. Irú iṣẹ́ ìránṣẹ́ yìí jẹ́ ojúlówó iṣẹ́ òjíṣẹ́ Ọlọ́run.- Counsels to Teachers,pp.547,548.IIO 66.2

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents