Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Láìmọ Tara-Ẹni-Nìkan

  Isé Kristi gbodò jé àwòkóse wa. Ni ´gbogbo ibi, ni ó lo káàkiri láti se rere. Nínú témpìlì àti Sínágógù, ní agboolé ìlú, ní ojà ní ibi iṣé, ní etí òkun àti lórí òkè. Ó wàásù ìhìnrere, Ó sì wo aláìsàn. Igbé ayé e Rè jé isé a-láì-fé-tara —eni- nìkan, ó sì gbodò jé ìwé èkó ọ wa. Ìwà ìrọnú àti ìkáánú ìfé Rè bá ìwà ìmò-tara-eni-nìkan àti àìnífè ẹ́ wa wí.-Tesimonies, Vol. 9, p. 31.IIO 242.3

  Ìdí tí a fi sisé f’Ólúwa ko gbodò jé torí ara wa rárá. Iṣé ìsìn àìmo-ara-eni àti èmí ìfara-eni-jìn jé, tí yóò sì má jé ohun àkọ́kó isẹ́ pàtàkì fún ìtéwógbà ìsìn wa lódò Olórun. Olúwa, Elédàá wa so pé kín-kín-ín nínú iṣé ìsìn wa kò ní wọ iṣẹ́ ẹ Rẹ̀. Nínú ìgbìyànjú wa, a gbudò fi ogbón àti ìmọ̀ wa pé Olórun aláṣepé ń fé lówó àwon olùkólé ìjosìn ayé, síbẹ̀ nínú iṣẹ́ ẹ wa a gbodò rántí pé èbùn tàbi ohun tí ó tóbi jùlo tàbi isé ìsìn tí ó dára jù jé ìtéwógbà nígbà tí a bá fi ara wa sílè bí ebo ààyè fún Olúwa (Prophet and King, p. 65).IIO 242.4

  Nínú gbogbo ènìyàn ayé, àwon alátúnse ni ó gbọdó jé a-láì-mo-tara-eni-nìkan jù, aláàánú àti onínú rere. A gbọdò rí ìwà rere àti isé àìmoaraeni nínú u won.-The Minissr of Healing, p. 157.IIO 242.5

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents