Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ìdílé Ìdíyelé

    À ń won iye isé tí a se fún Olórun nípa irú èmí tí a fi se é, kìí se bí isé ti pé tó.-Testimonies, Vol. 9, p. 74.IIO 266.4

    Àṣeyọrí i wọn nínú ẹ̀mí faralé ìtẹ̀síwájú wọn tàbí ìdàgbàsókè wọn nínú èbùn tí a fi fún wọn. A yóò fi èrè fún ọjọ́ ọ̀la nípa ìfìdímúlẹ̀ àti ìtara tí wọn fi sin Ọlọ́run.- Review and Herald, Mar. 1, 1887.IIO 266.5

    Oluwa ní iṣẹ́ ń lá láti ṣe yóò sì fún àwọn ènìyàn ní ojó iwájú, èyí ni àwọn tí ó gbàgbọ́ jùlọ, tí ó ṣetán láti ṣiṣẹ́ nínú ayé tí a wà yìí.- Christ Object Lessons, P.330.IIO 266.6

    Àwọn tí ó wọ inú ọgbà àjàrà ní àkókò tí ó kẹ́yìn pátápátá dúpé fún ànfààní láti ṣiṣẹ́. Ọ̀ràn a wọn kún fún ọpẹ́ sí ẹni tí ó gbà wọ́n nígbà tí ó san owó òde di ọjọ́ kan fún wọn èyí sì yà wọ́n lẹ́nu. Wọ́n mọ̀ pé àwọn yóò ṣiṣẹ́ tí ó yẹ fún owó iṣẹ́ tí ó san fún wọn, irú ọrẹ yìí mú wọn kún fún ayọ̀, tí wọn ó sì gbàgbé ore ẹni tí ó gbà wọ́n ṣíṣẹ́.IIO 266.7

    Bí ó ti rí pẹ̀lú àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ni èyí, láì mọ̀ pé àì pé, tí wọ inú ọgbà àjàrà Olúwa ní àkókò tí ó kẹ́yìn pátápátá, àsìkò ìsin rẹ̀ jẹ́ kékeré, o sì rò pé òun kò yẹ fún èrè, ṣùgbọ́n ó kún fún ayọ̀ pé Olọrun ti gba ohun. Ó ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ọkàn ìrẹ̀lẹ̀, ẹ̀mí tí ó gbàgbọ́, irú ọkàn yìí ni Ọlọ́run fẹ́ fún ní ẹ̀yẹ.- Christ’s Object Lessons, pp.397,398.IIO 267.1

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents