Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Aìfìyèsí Ìmẹ́lẹ́ Ṣíṣe

  Fífi ìwà ìmẹ́lẹ́ ṣe aláìkàsí àti ìwà àìgbàgbọ́ wà láàárín wa èyí tí ó sì ń fa ìfàsẹ́hìn láti ṣe iṣẹ́ èyí tí Ọlọ́run ti fifún wa látì ṣe nípa jíjẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ wa ó tàn sí ọ̀dọ̀ àwọn ará orílẹ̀ èdè mìíràn.-Life Sketches of Ellen G. White, p. 213.IIO 200.5

  A ti fi hàn mí wí pé, gẹ́gẹ́ bi ẹ̀dá ènìyàn, à ń sùn púpọ̀ sí àwọn ojúṣẹ wa nípa jíjẹ́ kí ímọ́lẹ̀ wa ó tàn sí ọ̀dọ̀ àwọn ará orílẹ̀ èdè mìíràn.-Life Sketches of Ellen G. White, p. 212.IIO 200.6

  A kò gbé ìgbésẹ̀ wa ní ìbámu pẹ̀lú àǹfààní tí Ọlọ́run ti pèsè sílẹ̀ fún wa. Jésù àti àwọn ańgẹ́lì wà lẹ́nu iṣẹ́. Iṣẹ́ náà sì ń tẹ̀síwájú nígbà tí àwa dúró sójú kan náà lẹ́hìn. Tí a bá lèè lo àǹfààní ìbùkún Ọlọ́run yìí, a ò leè lo ojú inú wa láti rí àwọn àǹfààní tí wọ́n ṣí sílẹ̀ tí a ó sì wá mú wọn lò bí ó ti tọ́ àti bí ó ti yẹ láti lèè jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ yìí ó tàn lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn elòmíràn.-Life Sketches of Ellen G. White, p. 212, 213.IIO 201.1

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents