Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    A Ti Fa Ọwọ́ Ìdálẹ́kun Ẹ̀mí Ọlọ́run sẹ́yìn

    Ìdálẹ́kun Ẹ̀mí Ọlọ́run ni a ti fa ọwọ́ ọ rẹ̀ sẹ́yìn nísinsinyìí, ìjì líle, ìjì, ẹ̀fúùfù líle, iná àti ẹ̀jẹ̀, àwọn ìjàm̀bá nípa òkun àti ilẹ̀, ń tẹ̀lé ara wọn ní ṣíṣẹ̀ n tẹ̀lé, ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ń wá láti ṣ’àlàyé gbogbo n nkan wọnyii. Àwọn àmìn wọ̀nyìí tó ń ṣẹ̀ ní àyíká a wa, ń fi sísúnmọ́ tòsí ọmọ ènìyàn han, ni a kà sí àmìn ohun mìíràn yàtọ̀ fún ohun tí ó jẹ́.Ènìyàn kò lè mọ áńgẹ́lì olùṣọ tí ó ń so orígun mẹ́rẹ̀rín ayé láti má jẹ̀ ẹ́ kí ó fọ́ títí tí àwọn ìránṣẹ́ Ọlọ́run yóò fi fi èdìdì dì í; Ṣùgbọ́n nígbà tí Ọlọ́run yóò pàṣẹ fún àwọn àńgẹ́lì i Rẹ̀ láti ti orígun yì ì. Ìṣẹ̀lẹ̀ ìjà tí a kò le è ṣàlàyé yóò ṣẹlẹ̀. Testimonies,Vol.6, p.408.IIO 52.2

    Àsìkò tí à ń gbé yì í lọ́wọ̀ ó sì ṣe pàtàkì. À ń gbá ẹ̀mí Ọlọ́run díẹ̀ díẹ̀ kúrò nínú ayè. Àjàkálẹ̀ àrùn àti ìdájọ́ tilẹ̀ ti ń bọ̀ sórí àwọn tí ó gan oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run. Jàm̀bá nípa ti ti ilẹ̀ àti òkun, àìní fọ̀kàn balẹ̀ ipò ti ẹgbẹ́, ìro ogun,jẹ amin isọtẹlẹ. Wọ́n ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ sísúnmọ́ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ń lá. Àwọn aṣojú u ti èṣù ń kó ara wọn jọ pọ̀ sógun, wọ́n ṣọ̀kan. Wọ́n ń ró wọn lágbára fún ìdàrú dàpọ̀ ìkẹhìn. Àyípadà ń lá láìpẹ́ yóò ṣẹlẹ̀ nínú ayé e wa, ìjáde lọ yóò sì jẹ́ kíà kíà.- Testimonies,vol.9,p.11.IIO 52.3

    Àsìkò náà súnmọ́ etílé nígbà tí ìkáàánú tàbí ìbànújẹ́ yóò wà nínú ayé tí kò sí ìkunra tí yóò le è wó sàn. Ẹ̀mí Olúwa ni a ti mú kúrò. Ìjàm̀bá lórí omi àti lórí ilẹ̀ ń tẹ̀lé ra ní ṣíṣẹ̀ n tẹ̀lé.Nígbàkúùgbà ni à ń gbọ́ nípa ilẹ̀ ríri tàbí ẹ̀fúùfù ń lá, ijamba nípa iná àti ìkún omi, pẹ̀lú ṣísòfò ẹ̀mí àti dúkìá! Ó hàn gbangba pé àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ yì í jẹ́ àyọrísí burúkú tí ìdàrúdàpọ̀, àti àílétò nínú àwọn agbára ìsẹ̀dá ṣokúnfá a rẹ́,èyí tí ó kọjá agbára ènìyàn; ṣùgbọ́n nínú u wọn, a le è kà nípa èrò Ọlọ́run.Wọ́n wà lára àwọn aṣojú nípa èyí tí yóò wá láti ta ọkùnrin àti obìnrin jí láti mọ̀ nípa ewu tí yóò wu wọ́n.- Prophets and Kings, p.277.IIO 52.4

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents