Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Àpẹẹrẹ Tí ó Yè

    Bóyá tálákà opó’bìnrin tí ó sọ owó idẹ wéwé méjì sínú àpótì ìsura Olúwa fi taratara mo ìtumò ohun tí ó se è nì nítorí àpeere ohun tí ó se è nì ó tí fi owó tó òpòlopò okàn ní orílè-èdè gbogbo jákèjádò àgbáyé. Ohun tí ó se èyí ní ó tí mú kí òpòlopò ó mú ore won wá sínú ìsura Olúwa yálà àwon tálákà tàbí olórò. Èyí sì tí mú kí isé Olúwa ó ní ìtèsíwájú yálà nípa kíkéde ìhìnrere ní tàbí kíkó ilé ìwòsàn ní tàbí bíbó àwon aláìní tàbí fífí aso fún àwon tí wón wà ní ìhòòho. Òpòlopò ní ó sì tí dí alábùkún fún nípa ìwà aláìní ìmo tara ení nìkan èyí tí ó tí hù yìí.- Testimonies, Vol. 6, p. 310.IIO 171.2

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents