Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ìjáfara L’éwu Púpọ̀

    A fihàn mí àwọn ènìyàn Ọlọ́run ń dúró fún ìyípadà láti ṣẹlẹ̀,-ki agbára ń lá kí ó fipá mú wọn. Ṣùgbọ́n wọn yóò ní ìjákulẹ̀, nítorí wọ́n ṣe àṣìṣe. Wọ́n gbọdọ̀ gbé ìgbésẹ̀, wọ́n gbọdọ̀ mú iṣẹ́ náà gírí tìkaára wọn, kí wọn sì kígbe tọkàn tọkàn fún ìmọ̀ tòótọ́ ọ ti ara wọn. Àwọn ìran tí ó kọjá niwaju u wa jẹ́ èyí tí ó tóbi láti lè mú wa tají, àti láti fi òtítọ́ rọ àwọn ọkàn tí ó fẹ́ láti tétí sílẹ̀. Ìkórè ayé fẹ́rẹ̀ ẹ́ pọ́n,-Testimonies,vol.1,p.261.IIO 43.3

    Ní ọ̀nà mìíràn, àwọn kan wà, dípò kí wọn lo ànfààní tí wọ́n ní láti ṣ’àtúnṣe, wọ́n dúró láì ṣe ohunkóhun fún àkókò tí a yà sọ́tọ̀ fún ìtura ẹ̀mí nípasẹ̀ èyí tí agbára ìlàlóye e wọn fún àwọn mìíràn yoo ṣe pọ̀ si.Wọ́n fi iṣẹ́ àtí ànfààní tí wọ́n fún wọn lọ́wọ́ lọ́wọ́ sílẹ̀ láì ṣe, wọ́n sì yọ̀ǹda iná a wọn láti máa wò bàì bàì, bí wọ́n ń wọ̀nà fún àsìkò nigba ti kò ní sí ìgbìyànjú kankan fún wọn mọ́,tí wọn yóò sì fi wọn ṣe olùgba ìbùkún pàtàkì, tí wọn yóò sì sọ wọ́n jí tí wọn yóò sì yẹ fún iṣẹ́ ìsìn.- The Acts of the Apostles, p.54.IIO 43.4

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents