Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Àwọn Àkànṣe Ètò Pàtàkì Ní Àwọn Ìpàdé Ìpàgọ́ Nígbà tí Òpin Bá Ń Súnmọ́

    A fi hàn mí wí pé àwọn ìpàgọ́ wa gbọ́dọ̀ máa pọ̀ si pẹ̀lú ìfẹ́ ọkàn àti àṣeyọrí. Bí òpin ayé ti ń súnmọ́ wa. Mo ti rí i wí pé nínú àwọn ìpàgọ́ wọ̀nyìí, kò gbọdọ̀ sí ìwàásù púpọ̀ bíkòṣe ìdànílẹ́kọ̀ọ́ láti inú Bíbélì. A gbọ́dọ̀ ní àwọn ẹgbẹ́ kékèèké ní gbogbo ìpàgọ́ pẹ̀lú Bíbélì wọn ní ọwọ́ wọn tí olúkúlukú wọn yóò sì máa kọ́ni gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.-Testimonies, Vol. 6, p. 87.IIO 197.2

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents