Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Àṣẹ Ìtẹ̀síwájú

    Aláṣẹ ti Wellington ni ó wà níbi tí ẹgbẹ́ àwọn ọkùnrin onígbàgbọ́ kan ti ń jíròrò nípa bí ó ṣe le ṣe é ṣe látí ṣe àṣeyọrí nínú ìgbìyànjú ìhìnrere láarin àwọn kèfèrí. Wọ́n pàrọwà sí alaṣẹ yii láti sọ bóyá nínú ìdájọ́ ọ rẹ̀ irú àwọn ìgbìyànjú yìí le e mu aṣeyọri ti o yẹ jade.IIO 77.3

    Ògbólógbò ó jagun jagun yìí dáhùn: “Ẹ̀yin arákùnrin, kíni àwọn àṣẹ ìtẹ̀síwájú u yín? Àṣeyọrí kìí ṣe ìbéèrè fún yín láti jíròrò lé lórí. Tí mo bá ka àṣẹ ẹ yín dáadáa, ó lọ báyìí, ” Ẹ lọ sí gbogbo ayé kí ẹ sì wàásù ìhìnrere fún gbogbo ẹ̀dá'. Arákùnrin, ẹ gbọ́ràn sí àṣẹ ẹ yín.”- Gospel Workers, p.115. IIO 77.4

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents