Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Láì sojúsáájú

  Bí Olùgbàlà wa se gbé láarin àwon ènìyàn ó, ní ó sì bá àwon òtòsì pín nínú ìpín won. Ó mò pèlú ìrírí ìjìyà won. Gbogbo àwon tí ó níse pèlú ìrèlè ni ó dùn nínú, tí ó sì gbìyànjú. Gbogbo àwon tí ó mo ìtumò ìjìnlè èkó Rè kì yóò fìgbà kan lérò pé ìyapa tàbí ìpínyà gbọdò wà láarin olówó àti otòsì, pé a gbọdò bòwò fún olówó ju tálákà lo.-The Desire of Ages, p. 73.IIO 241.4

  Nígbà tí ó bá kòyìn sí àwon tí ó dà bí enipé won kò ní ìlérí, tí wón sì fà móra, sé o mò pé ò ń se ìgbàgbé àwon okàn tí Olórun ń wá? Ní àkókò náà, tí o bá kòyìn, ó lè jé pé ìgbà náà ni won nílò àánú re. Ní gbogbo ìpéjo ìsìn, okàn pò tí ó ń wá ìsinmi àti àlàáfíà. Wón lè má gbé ìgbé ayé àìbìkítà, sùgbón won kò se aláìmò nípa Èmí Mímó. Òpòlopò won ni a lè gbà fún Kristi.- Christ’s Object Lesson. Ìpè sí ìhìnrere kìí se ohun tí ó fifún àwon ènìyàn díè tí a yàn, àwon tí a rò pé wón se wá lógo tí wón bá gba òrò nàá. — Christ’s Object Lessons, 191.IIO 241.5

  A gbọdò fi òrò náà ránsé sí gbogbo ènìyàn. Níbikíbi tí okàn bá sí sílè láti gba òtító, Olúwa setán láti kó won. —The Desire of Ages, p. 194.IIO 242.1

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents