Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ọ̀pọlọpọ̀ Ń dúró Fún Ìgbà Ìtura

    Òpòlopò tí ó ye kí won fi ogbón má lo ànfààní tí ó yojú sí won, ni ó ń dúró fún àsìkò òtò fún èmí-mímó, nígbà tí agbára won láti tan ìmólè sí elòmíràn yóò pò. Won fi isé tí ó ye kì won ó se sílè báyìí ohun ànfààní tí ó yojú síwon, wón sì jé kí ìmólè won kí ó rinlè, nígbà tí wón dúró de ìgbà tí won kò ní sapá kankan nípasè ara won láti gba ìbùkún òrò tí won kò fi yípadà àti ye fún isé ìsìn.-The Acts of Apostles, p. 54.IIO 255.2

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents